Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   ọ    February 25, 2023 at 01:36    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

1  GEN 1:1  Ní ìbẹ̀rẹ̀ ohun gbogbo ĺrun àwn ̀run àti ayé.
2  GEN 1:2  Ayé sì wà ní rúdurùdu, ó sì ṣófo, òkùnkùn sì wà lójú ibú omi, Ẹ̀mí ĺrun sì ń rábàbà lójú omi.
3  GEN 1:3  ĺrun sì wí pé, “Jẹ́ kí ìḿlẹ̀ kí ó wà,” ìḿlẹ̀ sì wà.
4  GEN 1:4  ĺrun rí i pé ìḿlẹ̀ náà dára, ó sì ya ìḿlẹ̀ náà śt̀ kúrò lára òkùnkùn.
5  GEN 1:5  ĺrun sì pe ìḿlẹ̀ náà ní̀sán,” àti òkùnkùn ní “òru.” Àṣálẹ́ àti òwúr̀ sì jẹ́ j́ kìn-ín-ní.
6  GEN 1:6  ĺrun sì wí pé, “Jẹ́ kí òfúrufú kí ó wà ní àárín àwn omi, láti pààlà sí àárín àwn omi.”
7  GEN 1:7  ĺrun sì dá òfúrufú láti ya omi tí ó wà ní òkè òfúrufú kúrò lára omi tí ó wà ní orí ilẹ̀. Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
8  GEN 1:8  ĺrun sì pe òfúrufú ní̀run.” Àṣálẹ́ àti òwúr̀ sì jẹ́ j́ kejì.
9  GEN 1:9  ĺrun sì wí pé, “Jẹ́ kí omi abẹ́ ̀run ẃ pap̀ sí ojú kan, kí ilẹ̀ gbígbẹ sì farahàn.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
10  GEN 1:10  ĺrun sì pe ilẹ̀ gbígbẹ náà ní “ilẹ̀,” àti àpap̀ omi ní “òkun.” ĺrun sì rí i wí pé ó dára.
11  GEN 1:11  ĺrun sì wí pé, “Jẹ́ kí ilẹ̀ kí ó hu ̀gbìn: ewéko ti yóò máa mú èso wá àti igi tí yóò máa so èso ní irú tirẹ̀, tí ó ní irúgbìn nínú.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
12  GEN 1:12  Ilẹ̀ sì hù ̀gbìn: ewéko tí ó ń so èso ní irú tirẹ̀, àti igi tí ń so èso, tí ó ní irúgbìn nínú ní irú tirẹ̀. ĺrun sì ri pé ó dára.
13  GEN 1:13  Àṣálẹ́ àti òwúr̀ sì jẹ́ j́ kẹta.
14  GEN 1:14  ĺrun sì wí pé, “Jẹ́ kí ìḿlẹ̀ kí ó wà ní ojú ̀run, láti pààlà sí àárín ̀sán àti òru, kí wn ó sì máa wà fún àmì láti m àwn àsìkò, àti àwn j́ àti àwn dún.
15  GEN 1:15  wn ó jẹ́ ìḿlẹ̀ ní ojú ̀run láti tan ìḿlẹ̀ sí orí ilẹ̀.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
16  GEN 1:16  ĺrun ìḿlẹ̀ ńlá ńlá méjì, ìḿlẹ̀ tí ó tóbi láti ṣe àkóso ̀sán àti ìḿlẹ̀ tí ó kéré láti ṣe àkóso òru. Ó sì dá àwn ìràẁ pẹ̀lú.
17  GEN 1:17  ĺrun sì ṣe ẃn ĺj̀ sí ojú ̀run láti máa tan ìḿlẹ̀ si orí ilẹ̀,
18  GEN 1:18  láti ṣàkóso ̀sán àti òru àti láti pààlà sí àárín ìḿlẹ̀ àti òkùnkùn. ĺrun sì rí i pé ó dára.
19  GEN 1:19  Àṣálẹ́ àti òwúr̀ sì jẹ́ j́ kẹrin.
20  GEN 1:20  ĺrun sì wí pé, “Jẹ́ kí omi kí ó kún fún àwn ohun alààyè, kí àwn ẹyẹ kí ó sì máa fò ní òfúrufú.”
21  GEN 1:21  Nítorí náà ĺrun àwn ẹ̀dá alààyè ńlá ńlá sí inú òkun, àwn ohun ẹlẹ́mìí àti àwn ohun tí ń rìn ní onírúurú tiwn, àti àwn ẹyẹ abìyẹ́ ní onírúurú tiwn. ĺrun sì rí i pé ó dára.
22  GEN 1:22  ĺrun súre fún wn, ó sì wí pé, “Ẹ máa bí sí i, ẹ sì máa p̀ sí i, ẹ kún inú omi òkun, kí àwn ẹyẹ náà sì máa p̀ sí i ní orí ilẹ̀.”
23  GEN 1:23  Àṣálẹ́ àti òwúr̀ sì jẹ́ j́ karùn-ún.
24  GEN 1:24  ĺrun sì wí pé, “Kí ilẹ̀ kí ó mú ohun alààyè jáde ní onírúurú wn: ẹran ̀sìn, àwn ohun afàyàfà àti àwn ẹran inú igbó, ̀k̀̀kan ní irú tirẹ̀.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
25  GEN 1:25  ĺrun sì dá ẹranko inú igbó àti ẹran ̀sìn gbogbo ní irú tirẹ̀ àti gbogbo ohun alààyè tí ń rìn ní ilẹ̀ ní irú tirẹ̀. ĺrun sì rí i pé ó dára.
26  GEN 1:26  Lẹ́yìn náà ni ĺrun wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a dá ènìyàn ní àwòrán ara wa, gẹ́gẹ́ bí àwa ti rí, kí wn kí ó jẹ ba lórí ẹja òkun, ẹyẹ ojú ̀run, ẹran ̀sìn, gbogbo ilẹ̀ àti lórí ohun gbogbo tí ń rìn lórí ilẹ̀.”
27  GEN 1:27  Nítorí náà, ĺrun dá ènìyàn ní àwòrán ara rẹ̀, ní àwòrán ĺrun ni ó dá a, ak àti abo ni ó dá wn.
28  GEN 1:28  ĺrun sì súre fún wn, ĺrun sì wí fún wn pé, “Ẹ máa bí sí i, kí ẹ sì máa p̀ sí i, kí ẹ sì gbilẹ̀, kí ẹ ṣe ìkápá ayé. Ẹ ṣe àkóso àwn ẹja inú òkun, ẹyẹ ojú ̀run àti gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ó ń rìn ní orí ilẹ̀.”
29  GEN 1:29  Nígbà náà ni ĺrun wí pé, “Mo fi gbogbo ohun ̀gbìn tí ń so èso fún un yín bí oúnjẹ àti àwn igi eléso pẹ̀lú. Gbogbo rẹ̀ yóò jẹ́ oúnjẹ fún un yín.
30  GEN 1:30  Àti fún àwn ẹranko inú igbó àti ẹyẹ ojú ̀run àti àwn ohun afàyàfà, gbogbo ohun tó ní èémí ìyè nínú ni mo fi ewéko fún bí oúnjẹ.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
31  GEN 1:31  ĺrun sì rí àwn ohun gbogbo tí ó dá, ó dára gidigidi. Àṣálẹ́ àti òwúr̀ sì jẹ́ j́ kẹfà.