Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   “Word-Word!    February 25, 2023 at 01:36    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

24188  MAT 26:65  Nígbà náà ni olórí àlùfáà fa aṣọ òun tìkára rẹ̀ ya. Ó sì kígbe pé, “Ọ̀rọ̀-òdì! Kí ni a tún ń wá ẹlẹ́rìí fún? Gbogbo yín ti gbọ́ ọ̀rọ̀-òdì rẹ̀. Kí ni ìdájọ́ yín?”