Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   Word—Word-Word,    February 25, 2023 at 01:36    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

6217  JOS 15:13  Gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Olúwa pa fún Joṣua, ó fi ìpín fún Kalebu ọmọ Jefunne, ìpín ní Juda—Kiriati-Arba, tí í ṣe Hebroni. (Arba sì ní baba ńlá Anaki.)