Wildebeest analysis examples for: yor-yor Word-Word),
February 25, 2023 at 01:36
Script wb_pprint_html.py by Ulf Hermjakob
6309
JOS 18:14
Láti òkè tí ó kọjú sí Beti-Horoni ní gúúsù ààlà náà yà sí gúúsù ní ìhà ìwọ̀-oòrùn, ó sì jáde sí Kiriati-Baali (tí í ṣe
Kiriati-Jearimu),
ìlú àwọn ènìyàn Juda. Èyí ni ìhà ìwọ̀-oòrùn.