Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   “Word”,    February 25, 2023 at 01:36    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

24273  MAT 28:9  Bí wọ́n ti ń sáré lọ lójijì Jesu pàdé wọn. Ó wí pé, “Àlàáfíà”, wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀. Wọ́n gbá a ní ẹsẹ̀ mú. Wọ́n sì foríbalẹ̀ fún un.