Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   (Word-Word    February 25, 2023 at 01:36    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

8866  1KI 4:19  Geberi ọmọ Uri ní Gileadi (orílẹ̀-èdè Sihoni ọba àwọn ará Amori àti orílẹ̀-èdè Ogu ọba Baṣani). Òun nìkan ni ìjòyè lórí ilẹ̀ náà.