Wildebeest analysis examples for: yor-yor (Word-Word)
February 25, 2023 at 01:36
Script wb_pprint_html.py by Ulf Hermjakob
10771
1CH 13:6
Dafidi àti gbogbo àwọn ọmọ Israẹli pẹ̀lú rẹ̀ lọ sí Baalahi ti Juda
(Kiriati-Jearimu)
láti gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run Olúwa tí a fi orúkọ rẹ̀ pè, tí ó jókòó láàrín kérúbù gòkè wá.