Wildebeest analysis examples for: yor-yor “Word:
February 25, 2023 at 01:36
Script wb_pprint_html.py by Ulf Hermjakob
21969
DAN 5:26
“Èyí ni nǹkan tí ọ̀rọ̀ náà túmọ̀ sí:
“Mene:
Ọlọ́run ti ṣírò ọjọ́ ìjọba rẹ. Ó sì ti mú u wá sí òpin.
21970
DAN 5:27
“Tekeli:
A ti gbé ọ lórí òsùwọ̀n, ìwọ kò sì tó ìwọ̀n.
21971
DAN 5:28
“Peresini:
A ti pín ìjọba rẹ a sì ti fi fún àwọn Media àti àwọn Persia.”