Wildebeest analysis examples for: yor-yor ‘Word’
February 25, 2023 at 01:36
Script wb_pprint_html.py by Ulf Hermjakob
54
GEN 2:23
Ọkùnrin náà sì wí pé, “Èyí ni egungun láti inú egungun mi àti ẹran-ara nínú ẹran-ara mi;
‘obìnrin’
ni a ó máa pè é, nítorí a mú un jáde láti ara ọkùnrin.”
26712
JHN 13:13
Ẹ̀yin ń pè mí ní
‘Olùkọ́’
àti ‘Olúwa,’ ẹ̀yin wí rere; bẹ́ẹ̀ ni mo jẹ́.