Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   ẹ    February 11, 2023 at 20:00    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

1  GEN 1:1  ìb̀r̀ ohun gbogbo Ọlọ́run dá àwọn ọ̀run àti ayé.
3  GEN 1:3  Ọlọ́run sì wí pé, “J́ ìmọ́l̀ kí ó wà,” ìmọ́l̀ sì wà.
4  GEN 1:4  Ọlọ́run rí i pé ìmọ́l̀ náà dára, ó sì ya ìmọ́l̀ náà sọ́tọ̀ kúrò lára òkùnkùn.
5  GEN 1:5  Ọlọ́run sì pe ìmọ́l̀ náà ní “ọ̀sán,” àti òkùnkùn ní “òru.” Àṣáĺ àti òwúrọ̀ sì j́ ọjọ́ kìn-ín-ní.
6  GEN 1:6  Ọlọ́run sì wí pé, “J́ kí òfúrufú kí ó wà ní àárín àwọn omi, láti pààlà sí àárín àwọn omi.”
7  GEN 1:7  Ọlọ́run sì dá òfúrufú láti ya omi tí ó wà ní òkè òfúrufú kúrò lára omi tí ó wà ní orí il̀. Ó sì rí b́̀.
8  GEN 1:8  Ọlọ́run sì pe òfúrufú ní “ọ̀run.” Àṣáĺ àti òwúrọ̀ sì j́ ọjọ́ kejì.
9  GEN 1:9  Ọlọ́run sì wí pé, “J́ kí omi ab́ ọ̀run wọ́ papọ̀ sí ojú kan, kí il̀ gbígb sì farahàn.” Ó sì rí b́̀.
10  GEN 1:10  Ọlọ́run sì pe il̀ gbígb náà ní “il̀,” àti àpapọ̀ omi ní “òkun.” Ọlọ́run sì rí i wí pé ó dára.
11  GEN 1:11  Ọlọ́run sì wí pé, “J́ il̀ kí ó hu ọ̀gbìn: ewéko ti yóò máa mú èso wá àti igi tí yóò máa so èso ní irú tir̀, tí ó ní irúgbìn nínú.” Ó sì rí b́̀.
12  GEN 1:12  Il̀ sì hù ọ̀gbìn: ewéko tí ó ń so èso ní irú tir̀, àti igi tí ń so èso, tí ó ní irúgbìn nínú ní irú tir̀. Ọlọ́run sì ri pé ó dára.
13  GEN 1:13  Àṣáĺ àti òwúrọ̀ sì j́ ọjọ́ kta.
14  GEN 1:14  Ọlọ́run sì wí pé, “J́ ìmọ́l̀ kí ó wà ní ojú ọ̀run, láti pààlà sí àárín ọ̀sán àti òru, kí wọn ó sì máa wà fún àmì láti mọ àwọn àsìkò, àti àwọn ọjọ́ àti àwọn ọdún.
15  GEN 1:15  Kí wọn ó j́ ìmọ́l̀ ní ojú ọ̀run láti tan ìmọ́l̀ sí orí il̀.” Ó sì rí b́̀.
16  GEN 1:16  Ọlọ́run dá ìmọ́l̀ ńlá ńlá méjì, ìmọ́l̀ tí ó tóbi láti ṣe àkóso ọ̀sán àti ìmọ́l̀ tí ó kéré láti ṣe àkóso òru. Ó sì dá àwọn ìràwọ̀ p̀lú.
17  GEN 1:17  Ọlọ́run sì ṣe wọ́n lọ́jọ̀ sí ojú ọ̀run láti máa tan ìmọ́l̀ si orí il̀,
18  GEN 1:18  láti ṣàkóso ọ̀sán àti òru àti láti pààlà sí àárín ìmọ́l̀ àti òkùnkùn. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.
19  GEN 1:19  Àṣáĺ àti òwúrọ̀ sì j́ ọjọ́ krin.
20  GEN 1:20  Ọlọ́run sì wí pé, “J́ kí omi kí ó kún fún àwọn ohun alààyè, kí àwọn y kí ó sì máa fò ní òfúrufú.”
21  GEN 1:21  Nítorí náà Ọlọ́run dá àwọn ̀dá alààyè ńlá ńlá sí inú òkun, àwọn ohun ĺmìí àti àwọn ohun tí ń rìn ní onírúurú tiwọn, àti àwọn y abìý ní onírúurú tiwọn. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.
22  GEN 1:22  Ọlọ́run súre fún wọn, ó sì wí pé, máa bí sí i, sì máa pọ̀ sí i, kún inú omi òkun, kí àwọn y náà sì máa pọ̀ sí i ní orí il̀.”
23  GEN 1:23  Àṣáĺ àti òwúrọ̀ sì j́ ọjọ́ karùn-ún.
24  GEN 1:24  Ọlọ́run sì wí pé, “Kí il̀ kí ó mú ohun alààyè jáde ní onírúurú wọn: ran ọ̀sìn, àwọn ohun afàyàfà àti àwọn ran inú igbó, ọ̀kọ̀ọ̀kan ní irú tir̀.” Ó sì rí b́̀.
25  GEN 1:25  Ọlọ́run sì dá ranko inú igbó àti ran ọ̀sìn gbogbo ní irú tir̀ àti gbogbo ohun alààyè tí ń rìn ní il̀ ní irú tir̀. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.
26  GEN 1:26  Ĺyìn náà ni Ọlọ́run wí pé, j́ kí a dá ènìyàn ní àwòrán ara wa, ǵǵ bí àwa ti rí, kí wọn kí ó j ọba lórí ja òkun, y ojú ọ̀run, ran ọ̀sìn, gbogbo il̀ àti lórí ohun gbogbo tí ń rìn lórí il̀.”
27  GEN 1:27  Nítorí náà, Ọlọ́run dá ènìyàn ní àwòrán ara r̀, ní àwòrán Ọlọ́run ni ó dá a, akọ àti abo ni ó dá wọn.
28  GEN 1:28  Ọlọ́run sì súre fún wọn, Ọlọ́run sì wí fún wọn pé, máa bí sí i, kí sì máa pọ̀ sí i, kí gbil̀, ṣe ìkápá ayé. ṣe àkóso àwọn ja inú òkun, y ojú ọ̀run àti gbogbo ̀dá alààyè tí ó ń rìn ní orí il̀.”
29  GEN 1:29  Nígbà náà ni Ọlọ́run wí pé, “Mo fi gbogbo ohun ọ̀gbìn tí ń so èso fún un yín bí oúnj àti àwọn igi eléso p̀lú. Gbogbo r̀ yóò j́ oúnj fún un yín.
30  GEN 1:30  Àti fún àwọn ranko inú igbó àti y ojú ọ̀run àti àwọn ohun afàyàfà, gbogbo ohun tó ní èémí ìyè nínú ni mo fi ewéko fún bí oúnj.” Ó sì rí b́̀.
31  GEN 1:31  Ọlọ́run sì rí àwọn ohun gbogbo tí ó dá, ó dára gidigidi. Àṣáĺ àti òwúrọ̀ sì j́ ọjọ́ kfà.
32  GEN 2:1  Báyìí ni Ọlọ́run parí dídá àwọn ọ̀run àti ayé, àti ohun gbogbo tí ó wà nínú r̀.
33  GEN 2:2  Ní ọjọ́ keje Ọlọ́run sì parí iṣ́ r̀ tí ó ti ń ṣe; ó sì sinmi ní ọjọ́ keje kúrò nínú iṣ́ r̀ gbogbo tí ó ti ń ṣe.
34  GEN 2:3  Ọlọ́run sì súre fún ọjọ́ keje, ó sì yà á sí mímọ́, nítorí pé ní ọjọ́ náà ni ó sinmi kúrò nínú iṣ́ dídá ayé tí ó ti ń ṣe.
36  GEN 2:5  Kò sí igi igbó kan ní orí il̀, b́̀ ni kò sí ewéko igbó kan tí ó tí ì hù jáde ní il̀, nítorí Olúwa Ọlọ́run kò tí ì rọ̀jò sórí il̀, kò sì sí ènìyàn láti ro il̀.
37  GEN 2:6  Ṣùgbọ́n ìsun omi ń jáde láti il̀, ó sì ń bu omi rin gbogbo il̀.
38  GEN 2:7  Olúwa Ọlọ́run sì fi erùp̀ il̀ mọ ènìyàn, ó si mí èémí ìyè sí ihò imú r̀, ènìyàn sì di alààyè ọkàn.
39  GEN 2:8  Olúwa Ọlọ́run sì gbin ọgbà kan sí Edeni ní ìhà ìlà-oòrùn, níb̀ ni ó fi ọkùnrin náà tí ó ti dá sí.
40  GEN 2:9  Olúwa Ọlọ́run sì mú kí onírúurú igi hù jáde láti inú il̀, àwọn igi tí ó dùn ún wò lójú, tí ó sì dára fún oúnj. Ní àárín ọgbà náà ni igi ìyè àti igi tí ń mú ènìyàn mọ rere àti búburú wà.