Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   Word’!”    February 11, 2023 at 20:00    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

9664  2KI 5:13  Ìránṣẹ́ Naamani lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ ó sì wí pé, “Baba mi, tí wòlíì bá ti sọ fún ọ láti ṣe ohun ńlá kan, ṣé ìwọ kì bá ti ṣe, mélòó mélòó nígbà náà, nígbà tí ó sọ fún ọ pé, ‘Wẹ̀ kí o sì mọ́’!”