Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   (Word,    February 11, 2023 at 20:00    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

19045  JER 2:11  Orílẹ̀-èdè kan ha á pa ọlọ́run rẹ̀ dà? (Síbẹ̀, wọ́n kì í ṣe iṣẹ́ ọlọ́run.) Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn mi ti pààrọ̀ Ọlọ́run ògo wọn fún àwọn ère tí kò níyì.