Wildebeest analysis examples for: yor-yor “Word”,
February 11, 2023 at 20:00
Script wb_pprint_html.py by Ulf Hermjakob
24273
MAT 28:9
Bí wọ́n ti ń sáré lọ lójijì Jesu pàdé wọn. Ó wí pé,
“Àlàáfíà”,
wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀. Wọ́n gbá a ní ẹsẹ̀ mú. Wọ́n sì foríbalẹ̀ fún un.