Wildebeest analysis examples for: yor-yor Word-Word-Word—
February 11, 2023 at 20:00
Script wb_pprint_html.py by Ulf Hermjakob
16150
PSA 121:1
Èmi yóò gbé ojú mi sórí òkè
wọ̀n-ọn-nì—
níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi yóò ti wá?
29960
TIT 1:1
Paulu, ìránṣẹ́ Ọlọ́run àti aposteli Jesu Kristi, gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ àwọn àyànfẹ́ Ọlọ́run àti ìmọ̀ òtítọ́ irú èyí tí í máa darí ènìyàn sí ìgbé ayé
ìwà-bí-Ọlọ́run—