Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   Word-Word—    February 11, 2023 at 20:00    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

18065  ISA 17:12  Kíyèsi i, ìrunú àwọn orílẹ̀-èdè— wọ́n ń runú bí ìgbì Òkun! Kíyèsi i, rògbòdìyàn tí ogunlọ́gọ̀ ènìyàn wọ́n bú ramúramù gẹ́gẹ́ bí ariwo odò ńlá!