Wildebeest analysis examples for: yor-yor Word.)”
February 11, 2023 at 20:00
Script wb_pprint_html.py by Ulf Hermjakob
23001
ZEC 4:10
“Ṣùgbọ́n ta ni ha kẹ́gàn ọjọ́ ohun kékeré? Nítorí wọn ó yọ̀ nígbà ti wọ́n bá rí okùn ìwọ̀n nì lọ́wọ́ Serubbabeli. “(Àwọn méje wọ̀nyí ni àwọn ojú Olúwa, tí ó ń sáré síyìn-ín sọ́hùn-ún ní gbogbo
ayé.)”