Wildebeest analysis examples for: yor-yor “Word?
February 11, 2023 at 20:00
Script wb_pprint_html.py by Ulf Hermjakob
24909
MRK 15:14
Nígbà náà ni Pilatu bi wọn léèrè pé,
“Èéṣe?
Búburú kí ni ó ṣe?” Wọ́n sì kígbe sókè gidigidi wí pé, “Kàn án mọ́ àgbélébùú!”
26159
JHN 1:46
Natanaeli béèrè pé,
“Nasareti?
Ohun rere kan ha lè ti ibẹ̀ jáde?” Filipi wí fún un pé, “Wá wò ó.”