Wildebeest analysis examples for:   yor-yor   Word-Word?’    February 11, 2023 at 20:00    Script wb_pprint_html.py   by Ulf Hermjakob

24726  MRK 11:17  Gẹ́gẹ́ bí ó ti kọ́ wọn, ó wí pé, “Ṣé a kò ti kọ ọ́ pé: ‘Ilé àdúrà ni a o máa pe ilé mi, ní gbogbo orílẹ̀-èdè?’ Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ti sọ ọ́ di ibùgbé àwọn ọlọ́ṣà.”